


Ela
Akeem Olabisi Ilupeju@akeemolabisiilupeju300449
6 months ago
#poetry
Ẹ̀là
(Odùu'fa kan tí ó ń jẹri sì ìwá s'aye Jésù Kristi àti ìpadàbọ̀ Rẹ̀. Translation of the Yorùbá version)
Ẹ̀là, rọ̀ wá!
Ẹ̀là, rọ̀ wá,!
Ẹ̀là, wá 'yé ọ wàá gbe'ku!
Ẹ̀là, wá 'yé ọ wàá gbe'ja!
Ẹ̀là wáy'é,
Ẹ̀là ó gbe'ku.
Ẹ̀là ó gbe'ja
Ẹ̀là gbá'yé ṣe rere.
.
Ayé bínú Ẹ̀là,
Ayé p'Ẹ̀là,
Ẹ̀là kú,
Ẹ̀là jíǹde,
Ẹ̀là gòkè ọ̀run lọ.
.
Ọmọ l'ójú Olódùmarè kàn ṣoṣo
To ń padà bọ̀ wá ṣe'dájọ ayé.
--------------------------------------------------------
Ẹ̀là
Copyright©2024.
Akeem Olabisi Ilupeju.
11 August, 2024.
All Rights Reserved.
--------------------------------------------------------


6 months ago

4 months ago

4 months ago