Alade Obafemi

Alade Obafemi
@aladeobafemi

1 year ago

ABÚLÉ ALÓWÀ

Lábúlé Alówà, Olóòtú sàwòn síbú...

Àwòn kínní gbé ikunmú Òbúko, gbogbo ìlú n se àhin. Ta lòbúko tí n gbénú ibú? Ta leni ilè tí n mí lábé omi?

Nínú ìrònú yi ni gbogbo Alówà wà fún ojó pípé. Njé kán kú so àwòn kejì sómi, kán mo ohun tó kù nínú ibú.

Àwòn kejì...

Ilè mì, síbè àwòn ò já. Kí gàn-an làwòn gbé tí n dérù balè? Ò di Okinni méta tí n jé BÍWÒKÓ. Bí ó sì ti dórí ilè, wón lo lótò.

Èrù de...

À fi ní ojó Àbáméta, ní ìròlé ayé. Alówà gba àlejò TÚMÒINÚ, ARÍRAN ÒRUN.

Ìtumò...

IPIN ÒBÚKO
ni àpeere ìwà ègbin tí n ènìyàn kòòkan n se sára ELÉDÙMARÈ.

IBÚ ni àpeere ELÉDÙMARÈ

Kínni OKINNI méta nì sàpere?

Èyí túnmòsí ayé méta; Òkan nínú ìyá, Èkejì nílé ayé. Èketa ni Àjùlé-Òrun.

© Alade Obafemi Babafemi.

29
59
1 year ago

Alade Obafemi

Sign in to post a comment.


Sign In